IJO ELETO NAIJIRIA, TONIIKI OJO ISIMI TI OSE KEJILELOGOJI (42 WEEK, 2026) - IBAGBEPO OLORUN AKÓRÍ EKÓ: IBAGBEPO OLORUN ÈSÈ WÚRÀ: ÈXODU 33:12-16 12 Mose sọ fún Olúwa pé, “Ìwọ ti ń sọ fún mi, ‘Darí àwọn ènìyàn wọ̀nyí,’ ṣùgbọ́n…
IJO ELETO NAIJIRIA, TONIIKI OJO ISIMI TI OSE OGOJI (40 WEEK, 2026) - JESU NI IPILE WA OSE /TONIIKI OGOJI AKÓRÍ ÈKÓ : JESU NI IPILE WA ÈSÈ WÚRÀ: MÁTÍÙ 21:33-44 33 “Ẹ gbọ́ òwe mìíràn: Baálé ilé kan tí ó gbin ọgbà àjàrà, ó ṣe ọgbà …
IJO ELETO NAIJIRIA, TONIIKI OJO ISIMI TI OSE YI, OSE KOKANDINLOGOJI (39 WEEK, 2026) - ORÚKO JESU OSE/ TONIIKI KOKANDINLOGOJI AKÓRÍ ĘKI: ORÚKO JESU ÈSÈ WÚRÀ : FILIPPI 2:6-11 6. Ẹni tí, bí o tilẹ̀ jẹ́ ìrísí Ọlọ́run, kò kà á sí oh…
IJO ELETO NAIJIRIA, TONIIKI OJO ISIMI TI OSE KETADINLOGOJI (37) - DARIJI AWON TO SE O IJO ELETO NAIJIRIA, TONIIKI OJO ISIMI QSE/ TONIIKI KETADINLOGOJI AKÓRÍ EKO : DARIJI AWON TO SE O ESÈ WÚRÀ : MÁTÍÙ 18:21-35 21 Nígbà náà ni Pe…